HAPPY SUNDAY!! PRAYER POINTS FOR TODAY PRAY WITH PSALMS 5*

 

1. I thank the Lord for You are the only one that answers prayer.

2. Every poison and contamination in my blood, be flushed out.

3. I receive wisdom and power to surpass all
competitors in Jesus’ name.

4. I bind and paralyze every spirit of labour loss in Jesus’ name.

5. Anointing to excel, possess me in Jesus’ name.

6. I reject every curse of failure in Jesus’ name.

7. Every spirit of immediate gratification, loose your
hold over my children and be wasted.

8. I thank You Jesus for answers to prayers.

*KOKO ADURA FUN 16/10/21 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 5*

1. MODUPE, l’owo Oluwa nitori oun nikan lo n gbo
adura.

2. Gbogbo majele ati ibaje ninu eje mi, fo jade.

3. Mo gba ogbon ati agbara lati tayo ju awon abanidije
mi lo ni oruko Jesu.

4. Mo de, mo si yalaro gbogbo emi ti n mu ni sise lasan l’oruko Jesu.

5. Ifami ororo yan lati tayo, gbe mi wo l’oruko Jesu.

6. Mo ko gbogbo egun ijakule l’oruko Jesu.

7. Gbogbo emi ere ni kiakia, so agbara re nu l’ori aiye emi ati awon omo mi ki os si s’ofo danu.

8. Modupe l’owo Re Jesu fun idahun adura.


RELATED POSTS



ALL ARTISTE/POST TAGS: 👇


Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*